Gbajugbaja oniwaasu ati oludasilẹ ijọ Christ Apostolic Church (CAC), Woli Micheal jo Olowere, ti ọpọ mọ si ‘’Baba Automatic’’ ti jade laye. Olowere ni oludasilẹ ijọ CAC, Oke Agbara, ni agbegbe Ashi ni ...