Aipẹ yii ni ọrọ emi lagba, emi ni mo ju ọ, waye laaarin Alaafin Oyo; Oba Abimbola Owoade ati Ooni Ile-Ife; Oba Adeyeye Ogunwusi. Ni bayii, Ataoja Osogbo ati Oluwoo ti ilu Iwo, nipinlẹ Osun ni wọn tun ...
Awọn oludibo bii ogoji miliọnu ni yoo jade lati dibo yan aarẹ tuntun ni orilẹede Democratic Republic of Congo (DRC), ni ogunjọ, oṣu Kejila, ọdun 2023. Aarẹ Felix Tshisekedi lo n dije fun saa keji, ti ...